WordPress.org

Nípa

Roadmap

Roadmap

WordPress wà ní ìdàgbàsókè nígbà gbogbo. Lọ́wọ́lọ́wọ́, Apá 2 iṣẹ́ àkànṣe Gutenberg ti parí pẹ̀lú WordPress 6.3, àti pé ìwáàdí Apá 3 (Ìfọwọ́sowọ́pọ̀) ti bẹ̀rẹ̀. Iṣẹ́ àkànṣe Gutenberg jẹ́ àtúnyẹ̀wò ọ̀nà tí a fi ń ṣàkóso àkóónú lórí web. Góńgó rẹ̀ ni láti fa ààyè sí wíwà lórí web gbòòrò, èyí tí ó jẹ́ ìpìlẹ̀ àwọn ìṣòwò ìgbàlódé tó yọrí sí àṣeyọrí.

Phase 1 was the new block editor, Gutenberg, released in WordPress 5.0. In 2021 and 2022, we focused on merging Site Editing (Phase 2) into WordPress. This introduced the Site Editor and a suite of editing capabilities that enable leveraging blocks for use across an entire website. Phase 3 is Collaborative Editing, also known as Workflows given its implementation of features for workflows and real-time collaboration. Check out the Feature Projects Overview page for more information on site editing, its components, and other active feature work.

To support the vision set in the latest State of the Word, the project has the following big picture goals:

Ṣé o fẹ́ kópa? Lọ sí Make WordPress kí o sì pàdé àwọn ènìyàn tó ń ṣe ìdàgbàsókè, ìṣẹ̀dá, àkọsílẹ̀, ìtumọ̀, àti títajà WordPress.

Awọn itusilẹ ti n bọ

Plans for future releases will be timely communicated. Follow changes in progress for the next major version in our issue tracker. Projected dates below are for rough planning purposes only.

VersionPlanned
7.0Lododun 2026 (apejuwe)

New features are frozen a month before a release, with the focus shifting entirely to the quality and performance of the release.

You can see a list of past releases on our history page.

Long term roadmap

As a reminder, these are the four phases outlined in the Gutenberg project:

  1. Easier Editing — Already available in WordPress, with ongoing improvements
  2. Customization — Site Editing, block patterns, block directory, block themes
  3. Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ — Ọ̀nà tó túbọ̀ ṣe é gbọ́ yé láti jọ kọ àkóónú
  4. Multilingual — Core implementation for Multilingual sites