Redfoo
Ìrísí
| Redfoo | |
|---|---|
Redfoo ní ọdún 2011 | |
| Ọjọ́ìbí | Stefan Kendal Gordy Oṣù Kẹ̀sán 3, 1975 Los Angeles, California, U.S. |
| Iṣẹ́ |
|
| Parent(s) | Berry Gordy |
| Musical career | |
| Irú orin | |
| Years active | 1993–present |
| Labels | Party Rock, Interscope |
| Associated acts | LMFAO |
Stefan Kendal Gordy (bíi ní Oṣù Chepteba 3, 1975), tí a mọ̀ sí Redfoo, jẹ́ akọrin, rapper, àti agbábọ́ọ̀lù tẹ́nìsì ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Ìgbésí ayé àti Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2006, ó dá ẹgbẹ́ orin electropop LMFAO sílẹ̀ pẹ̀lú ọmọ arákùnrin rẹ̀ SkyBlu. Wọ́n gbé àwo orin meji síta kí wọ́n tó pín yà ní ọdún 2012. Ó jẹ́ ọmọ kíkéré jùlọ ti Berry Gordy, olùdásílẹ̀ Motown Records.
Ní ọdún 2025, ó di agbábọ́ọ̀lù tẹ́nìsì oníṣẹ́ gidi.
Àwo orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Balance Beam (1997)
- Party Rock (2009)
- Sorry for Party Rocking (2011)
- Party Rock Mansion (2016)